Sáàmù 77:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo rántí orin mi ní òru.Èmi ń bá àyà mí sọ̀rọ̀,ọkàn mí sì ń ṣe àwárí jọjọ.

Sáàmù 77

Sáàmù 77:1-14