Sáàmù 77:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi rántí i Rẹ, Ọlọ́run,mo sì kẹ́dùn;mo ṣe àroyé, ẹ̀mí mi sì rẹ̀wẹ̀sì. Sela

Sáàmù 77

Sáàmù 77:1-6