Sáàmù 76:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ nìkan ni o yẹ kí a bẹ̀rù.Ta ló lé dúró níwájú Rẹ nígbà tí ìwọ bá ń bínú?

Sáàmù 76

Sáàmù 76:1-10