Sáàmù 76:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lóòtọ́, ìbínú Rẹ̀ sí àwọn ènìyàn ń mú ìyìn wá fún ọ,ẹni tí ó yọ nínú ìbínú Rẹ ní a dá nígbà tí ìwọ bá fi ìbínú ìyókù di ara Rẹ ni àmùrè.

Sáàmù 76

Sáàmù 76:1-12