Sáàmù 73:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí èmi ń ṣe ìlara àwọn tó ń ṣeféfénígbà tí mo bá rí ọlá àwọn ènìyàn búburú.

Sáàmù 73

Sáàmù 73:1-9