Sáàmù 71:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo gbẹ́kẹ̀lé ọ láti ìgbà ìbí mi;Ìwọ mu mi jáde láti inú ìyá mi wáèmi ó máa yìn ọ títí láé

Sáàmù 71

Sáàmù 71:1-11