Sáàmù 71:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pẹ̀lúpẹ̀lú ìwọ ti mú mi rí ìdààmú, tí o pọ̀ tí ó sì korò,ìwọ yóò tún sọ ayé mi jíìwọ yóò sì tún mú mi sọ sókèláti ọ̀gbun ilẹ̀ wá.Ìwọ yóò sọ ọlá mi di púpọ̀

Sáàmù 71

Sáàmù 71:13-22