Sáàmù 71:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí àwọn ọ̀tá mi ń sọ̀rọ̀ òdì sí miàwọn tí wọn dúró láti pa mí gbìmọ̀ pọ̀

Sáàmù 71

Sáàmù 71:5-17