Sáàmù 69:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí Ọlọ́run yóò gba Síónì làyóò sì tún àwọn ìlú Júdà wọ̀nyí kọ́.Kí wọn ó lè máa gbé ibẹ̀,kí wọn ó lè máa níi ni ilẹ̀ ìní

Sáàmù 69

Sáàmù 69:26-36