Sáàmù 69:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n fi òróró fún mi pẹ̀lú ohun jíjẹ mi,àti ní òungbẹ mi, wọn fi ọtí kíkan fún mi.

Sáàmù 69

Sáàmù 69:19-28