Sáàmù 68:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kọrin sí Ọlọ́run,ẹ kọrin ìyìn síi,ẹ la ọ̀nà fún ẹni tí ń ré kọjá ní ihà.JAH ni orúkọ Rẹ̀, kí ẹ sì máa yọ̀ níwájú Rẹ̀.

Sáàmù 68

Sáàmù 68:1-5