Sáàmù 68:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bá àwọn ẹranko búburú wí,tí ń gbé láàrin ìkoọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn akọ màlúùpẹ̀lú àwọn ọmọ màlúùtítí olúkúlùkù yóò fi forí balẹ̀ pẹ̀lú ìwọn fàdákà:tú àwọn orílẹ̀-èdè ti ń ṣe inú dídùn si ogun ká

Sáàmù 68

Sáàmù 68:22-35