Sáàmù 68:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olùbùkún ni Ọlọ́run,sí Ọlọ́run Olùgbàlà wa,ẹni tí ó ń fi ojojúmọ́ gba ẹrù wa rù. Sela

Sáàmù 68

Sáàmù 68:12-28