Sáàmù 68:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá ní kẹ̀kẹ́ ogun Ọlọ́runẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹgbẹ̀rún; Olúwa ń bẹ láàrin wọn ní Sínáì ni ibi mímọ́ Rẹ̀.

Sáàmù 68

Sáàmù 68:14-18