Sáàmù 68:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí Ọlọ́run kí o dìde, kí àwọn ọ̀ta Rẹ̀ kí ó fọ́nká;kí àwọn ọ̀ta Rẹ̀ kí ó sá níwájú Rẹ̀.

Sáàmù 68

Sáàmù 68:1-10