Sáàmù 66:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ wá gbọ́ gbogbo ẹ̀yin tí ó bẹ̀rù Olúwa;ẹ jẹ́ kí n sọ ohun tí ó ṣe fún mi.

Sáàmù 66

Sáàmù 66:10-17