Sáàmù 64:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n tafà ní kọ̀kọ̀ sí àwọn aláìlẹ́ṣẹ̀:wọ́n tafà sí lojijì, wọn kò sì bẹ̀rù.

Sáàmù 64

Sáàmù 64:1-10