Sáàmù 64:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pa mí mọ́ kúrò lọ́wọ́ ìmọ̀ ìkọ̀kọ̀ àwọn ènìyàn búburúkúrò nínú ọ̀pọ̀ igbe lọ́wọ́ ìrúkèrúdò oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀.

Sáàmù 64

Sáàmù 64:1-9