Sáàmù 63:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi o yìn ọ́ níwọ̀n ìgbà tí mo wà láàyè,èmi ó gbé ọwọ́ sókè, èmi ó sì pe orúkọ Rẹ.

Sáàmù 63

Sáàmù 63:1-6