Sáàmù 62:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kìkì èró wọn ni láti bì ṣubúkúrò nínú ọlá Rẹ̀;inú wọn dùn sí irọ́.Wọn ń fi ẹnu wọn súre,ṣùgbọ́n wọ́n ń gégùn nínú ọkàn wọn. Sela

Sáàmù 62

Sáàmù 62:1-7