Sáàmù 62:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú Ọlọ́run nìkan ni ọkàn mi ti rí ìsinmi;ìgbàlà mi ti ọ̀dọ̀ Rẹ̀ wá.

Sáàmù 62

Sáàmù 62:1-10