Sáàmù 6:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kúrò lọ́dọ̀ mi, gbogbo ẹ̀yin tí ń ṣe iṣẹ́ ibi,nítorí Olúwa ti gbọ́ igbe mi.

Sáàmù 6

Sáàmù 6:1-9