Kíyèsí ohun tí wọ́n tú jáde ní ẹnu:wọn ń tú idà jáde láti ètè wọn,wọn sì wí pé, “Ta ní ó le gbọ́ ọ̀rọ̀ wa?”