Sáàmù 58:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀rọ̀ wọn dà bí ọ̀rọ̀ ejò,gẹ́gẹ́ bí ti sèbé tí ó dítí Rẹ̀,wọn dàbí adití ejò paramọ́lẹ̀ tí ó di ara Rẹ̀ ni etí

Sáàmù 58

Sáàmù 58:1-8