Sáàmù 58:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ kọ́, nínú ọkàn yín ẹ̀yìn ń gbèrò àìsòdodo,Ọmọ yín sì tú ìwà ipá jáde ni ayé.

Sáàmù 58

Sáàmù 58:1-10