Sáàmù 57:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó máa yín ọ, Olúwa, láàrin àwọn orílẹ̀ èdè;èmi ó máa kọrin sí ọ láàrin àwọn ènìyàn.

Sáàmù 57

Sáàmù 57:1-11