Wọn ti ta àwọ̀n sílẹ̀ fún ẹsẹ̀ mi:a tẹ orí ọkàn mi ba nínú ìtìjúwọ́n gbẹ́ kòtò sí ọ̀nà mi:ṣùgbọ́n wọn ti jìn ṣíbẹ̀ fún ara wọn.