Òun yóò ránsẹ́ láti ọ̀run wá,yóò sì gbà mí bí ẹni tí ń fẹ́ gbé mì mìtilẹ̀ ń kẹ́gàn mi.Ọlọ́run yóò rán àánú Rẹ̀ àti òdodo Rẹ̀ jáde.