Sáàmù 56:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni àwọn ọ̀tá mi yóò pẹ̀yìndànígbà tí mo bá pè fún ìrànlọ́wọ́nípa èyí ní mo mọ̀ pé Ọlọ́run ń bẹ fún mi

Sáàmù 56

Sáàmù 56:2-13