Sáàmù 55:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní alẹ́, ní òwúrọ̀ àti ní ọ̀sánèmi sunkún jáde nínú ìpọ́njú,o sì gbọ́ ohùn mi.

Sáàmù 55

Sáàmù 55:7-23