Sáàmù 55:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ikú kí ó dé bá wọn,Kí wọn ó lọ láàyè sí isà òkú,Jẹ́ kí wọn ó sọ̀kalẹ̀ sí ibojì pẹ̀lú ìpayà,nítorí tí ìwà búburú ń bẹ ní ibùjókòó wọn, àti nínú wọn.

Sáàmù 55

Sáàmù 55:11-23