Sáàmù 54:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí ibi padà sẹ́yìn sí àwọn tí ń sọ̀rọ̀ ìbàjẹ́ sí mi;pa wọ́n run nínú òtítọ́ Rẹ.

Sáàmù 54

Sáàmù 54:3-7