Ìgbàlà Ísírẹ́lì ìbá jáde wá láti Síónì!Nígbà tí Ọlọ́run bá mú ohun ìní àwọn ènìyàn Rẹ̀ padà,jẹ́ kí Jákọ́bù yọ̀ kí inú Ísírẹ́lì sì máa dùn!