Sáàmù 51:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní tòótọ́, nínú ẹ̀ṣẹ̀ ni a ti bí mi,nínú ẹ̀ṣẹ̀ ni ìyá mí sì lóyún mi.

Sáàmù 51

Sáàmù 51:2-15