Sáàmù 51:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbàmí kúrò lọ́wọ́ ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀, Ọlọ́run,ìwọ Ọlọ́run ìgbàlà mi,ahọ́n mi yóò sì máa kọrin òdodo Rẹ kíkan.

Sáàmù 51

Sáàmù 51:9-19