Sáàmù 51:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe jù mi nù kúrò níwájú Rẹ̀kí o má ṣe gba ẹ̀mí mímọ́ Rẹ̀ lọ́wọ́ mi.

Sáàmù 51

Sáàmù 51:7-17