Sáàmù 50:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kí yóò bá ọ wínítorí àwọn ìrúbọ Rẹ̀tàbí ọrẹ̀ ẹbọ sísun Rẹ, èyí tí ó wà níwájú miní ìgbà gbogbo.

Sáàmù 50

Sáàmù 50:6-18