Sáàmù 50:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ebi tílẹ̀ ń pá mí, èmi kì yóò sọ fún ọ,nítorí ayé ni tèmi àti ohun gbogbotí ó wa ní inú Rẹ̀.

Sáàmù 50

Sáàmù 50:7-20