Sáàmù 5:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dá wọn lẹ́bi Ọlọ́run!Jẹ́ kí rìkísí wọn jẹ́ ìṣubú wọn.Lé wọn jáde nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ṣẹ̀ wọn,nítorí wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí ọ.

Sáàmù 5

Sáàmù 5:5-12