Sáàmù 49:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ibojì wọn ni yóò jẹ́ ilé wọn láéláéibùgbé wọn láti ìrandé ìranwọn sọ orúkọ ilẹ̀ wọn ní orúkọ ara wọn

Sáàmù 49

Sáàmù 49:3-14