Sáàmù 48:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí Ọlọ́run yìí Ọlọ́run wà ní títí ayéÒun ni yóò ṣe amọ̀nà wa títí dè òpin ayé.

Sáàmù 48

Sáàmù 48:9-14