Sáàmù 45:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ọlá-ńlá Rẹ máa gẹṣin lọ ní àlàáfíàlórí òtítọ́, ìwà tútù àti òtítọ́jẹ́ kí ọwọ́ ọ̀tún Rẹ ṣe ohun ẹ̀rù

Sáàmù 45

Sáàmù 45:1-6