Sáàmù 45:15-17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. Wọ́n sì mú un wá pẹ̀lú ayọ̀ àti inú dídùnwọ́n sì wọ ààfin ọba.

16. Ọmọ Rẹ̀ ni yóò gba ipò baba Rẹ̀ìwọ yóò sì fi wọ́n joyè lórí ilẹ̀ gbogbo.

17. Èmí yóò máa rántí orúkọ Rẹ̀ ní ìran gbogbonígbà náà ni orílẹ̀ èdè yóò yìn ọ́ láé àti láéláé.

Sáàmù 45