Sáàmù 45:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ògo ni ti ọmọbìnrin ọba ní àárin ilé Rẹ̀aṣọ ìbalẹ̀ Rẹ̀ a ṣe é lọ́sọ̀ọ́ pẹ̀lú wúrà

Sáàmù 45

Sáàmù 45:6-15