Sáàmù 45:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọkàn mi mọ ọ̀rọ̀ reregẹ́gẹ́ bí mo ṣe ń sọ ohuntí mo ti ṣe fún ọbaahọ́n mi ni kálámù ayára kọ̀wé.

2. Ìwọ yanjú ju àwọn ọmọ ènìyàn lọ:a da oore-ọ̀fẹ́ sí ọ ní ètè:nítorí náà ni Ọlọ́run ṣe bùkún fún ọ láéláé.

3. Gba idà Rẹ mọ́ ìhà Rẹ, ìwọ alágbára jùlọwọ ara Rẹ̀ ní ògo àti ọla ńlá.

Sáàmù 45