Sáàmù 44:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nísinsìnyí ìwọ ti kọ̀ wá, ìwọ sì ti dójútì wá;Ìwọ kò sì bá àwọn ọmọ ogun wa jáde mọ́.

Sáàmù 44

Sáàmù 44:3-19