Sáàmù 44:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ìwọ fún wa ní ìṣẹ́gun lórí àwọn ọ̀tá wa,ìwọ sì ti dójúti àwọn tí ó kórìíra wa.

Sáàmù 44

Sáàmù 44:1-14