Sáàmù 44:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìdójútì mi ń bẹ pẹ̀lú mi ní gbogbo ọjọ́,ìtìjú sì bojú mi mọ́lẹ̀,

Sáàmù 44

Sáàmù 44:5-21