Sáàmù 44:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ta àwọn ènìyàn Rẹ fún owó kékeré,Ìwọ kò sì jẹ èrè kankan lórí iye tí ìwọ tà wọ́n.

Sáàmù 44

Sáàmù 44:11-14