Sáàmù 44:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti fi ètí wa gbọ́, Ọlọ́runàwọn baba wa tí sọ fún waoun tí ìwọ ṣe ní ọjọ́ wọn,ní ọjọ́ pípẹ́ sẹ́yìn.

Sáàmù 44

Sáàmù 44:1-7